globe

Awon akeko ko iroyin ni ona pupo merinla (14) ti ile eko giga fasiti ti ilu Miami ni Amerika parapo pelu awon akeko Seven Night Centre for international Media Partner school ni Afirika ati Asia lati so iroyin ti o je mo ilepa idagbasoke igbalode ti gbogbo orile ede ti n be ni agbaye.(United Nations Millennium Development Goals). Ni ibasepo pelu Tom Kennedy, Knight Centre Professional-in-Residence, egbe Kookan awon akeko yii wa ekunrere iroyin agbegbe ti o se alaye nipa awon ohun ti o koni lominu ni agbaye, bi Ise, ilera awon abiamo, Agbegbe ti o see gbe, Eto eko fun gbogbo eniyan, Sise itoju okunrin ati obinrin laisi oju isaju, Arun kogboogun HIV AIDS ati ilera awon omode.